Asa — Paroles et traduction des paroles de la chanson Grateful
La page contient les paroles et la traduction française de la chanson « Grateful » de Asa.
Paroles
Era ile, era ile
Won yin baba l’oke
Yanrin okun, yanrin okun
Won n yin baba l’oke
Eranko ile, eranko igbo Won n yin baba l’oke
Awon alaini, awon tan ti ni Won yin baba l’oke
Ko se igbati nkan ba se yan
Ko to mo pe baba n be l’oke
Ko se igbati nkan ba se yan
Ko to mo pe looto o n be l’oke
You don’t have to wait till you feel the pain
You can start right now
It’s not too late
It’s not too late, to be grateful
Era ile, era ile,
Won yin baba l’oke
Yanrin okun, yanrin okun
Won yin baba l’oke
Pe mo wa laye, mo wa laye
Gbogbo n ti mo ni, ma fin yi o l’ogo
Believe this world a better place
Wo mi, bi mo se n f’ope ye baba
Da di da dada
Da di da dudu
Da di da dada
Da di da dudu
It’s not too laaate
Traduction des paroles
L'ère de l'ile, era ile
Won Yin baba l'Oke
Yanrin okun, yanrin okun
Won n Yin baba l'Oke
Eranko ile, eranko igbo Won n Yin baba l'Oke
Awon alaini, awon tan ti Ni Won Yin baba l'Oke
Ko se igbati Nkan ba se yan
Ko à mo pe baba n l'oke
Ko se igbati Nkan ba se yan
Ko à mo pe looto o n l'oke
Vous n'avez pas à attendre que vous ressentiez la douleur
Vous pouvez commencer dès maintenant
Il n'est pas trop tard
Il n'est pas trop tard, pour être reconnaissant
L'ère de l'ile, era ile,
Won Yin baba l'Oke
Yanrin okun, yanrin okun
Won Yin baba l'Oke
Pe mo wa Laye, mo wa laye
Gbogbo n ti mo ni, ma fin yi o l'OGO
Croyez ce monde un meilleur endroit
Wo mi, bi mo se n f'ope vous baba
Da di da dada
Da di da Dudu
Da di da dada
Da di da Dudu
Ce n'est pas trop laaate